Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 6:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n gbé àpótí ẹ̀rí náà wọnú ìlú, wọ́n sì gbé e sí ààyè rẹ̀, ninu àgọ́ tí Dafidi ti kọ́ sílẹ̀ fún un. Dafidi sì rú ẹbọ sísun ati ẹbọ alaafia sí OLUWA.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 6

Wo Samuẹli Keji 6:17 ni o tọ