Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 6:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọ́n ti gbé àpótí ẹ̀rí náà wọ inú ìlú Dafidi, Mikali ọmọ Saulu yọjú wo òde láti ojú fèrèsé, ó rí Dafidi ọba tí ó ń jó tí ó sì ń fò sókè níwájú OLUWA, Mikali sì kẹ́gàn rẹ̀ ninu ọkàn rẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 6

Wo Samuẹli Keji 6:16 ni o tọ