Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 5:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọdún meje ati oṣù mẹfa ni ó fi jọba lórí ẹ̀yà Juda ní Heburoni. Lẹ́yìn náà, ó wá sí Jerusalẹmu ó sì jọba lórí gbogbo Israẹli ati Juda fún ọdún mẹtalelọgbọn.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 5

Wo Samuẹli Keji 5:5 ni o tọ