Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 3:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi bá dáhùn pé, “Ó dára, n óo bá ọ dá majẹmu. Ṣugbọn nǹkankan ni mo fẹ́ kí o ṣe, o kò ní fi ojú kàn mí, àfi bí o bá mú Mikali ọmọbinrin Saulu lọ́wọ́ nígbà tí o bá ń bọ̀ wá rí mi.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 3

Wo Samuẹli Keji 3:13 ni o tọ