Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 3:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Abineri bá ranṣẹ sí Dafidi ní Heburoni pé, “Ṣebí ìwọ ni o ni ilẹ̀ yìí? Bá mi dá majẹmu, n óo wà lẹ́yìn rẹ, n óo sì mú kí gbogbo Israẹli pada sọ́dọ̀ rẹ.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 3

Wo Samuẹli Keji 3:12 ni o tọ