Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 24:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ré odò Jọdani kọjá, wọ́n pàgọ́ sí ìhà gúsù Aroeri, ìlú tí ó wà ní ààrin àfonífojì, ní agbègbè Gadi. Láti ibẹ̀ ni wọ́n ti lọ sí ìhà àríwá, títí dé Jaseri.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 24

Wo Samuẹli Keji 24:5 ni o tọ