Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 23:5 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bẹ́ẹ̀ ni yóo rí fún arọmọdọmọ mi níwájú Ọlọrun,nítorí pé, ó ti bá mi dá majẹmu ayérayé nípa ohun gbogbo,majẹmu tí kò lè yipada, ati ìlérí tí kò ní yẹ̀.Yóo ṣe ohun tí mo fẹ́ fún mi.Yóo ràn mí lọ́wọ́, yóo fún mi ní ìfẹ́ ọkàn mi.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 23

Wo Samuẹli Keji 23:5 ni o tọ