Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 21:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn èyí, ogun mìíràn tún bẹ́ sílẹ̀ pẹlu àwọn ará Filistia, ní Gobu, ninu ogun yìí ni Sibekai ará Huṣa ti pa Safu, ọ̀kan ninu àwọn ìran òmìrán.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 21

Wo Samuẹli Keji 21:18 ni o tọ