Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 21:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Abiṣai, ọmọ Seruaya, sáré wá láti ran Dafidi lọ́wọ́, ó kọlu òmìrán náà, ó sì pa á. Láti ìgbà náà ni àwọn ọmọ ogun Dafidi ti búra fún un pé, “A kò ní jẹ́ kí o bá wa lọ sí ojú ogun mọ́ kí á má baà pàdánù rẹ, nítorí pé ìwọ ni ìrètí Israẹli.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 21

Wo Samuẹli Keji 21:17 ni o tọ