Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 2:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Abineri tún pe Asaheli, ó tún sọ fún un pé, “Pada lẹ́yìn mi, má jẹ́ kí n pa ọ́? Ojú wo ni o sì fẹ́ kí n fi wo Joabu ẹ̀gbọ́n rẹ?”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 2

Wo Samuẹli Keji 2:22 ni o tọ