Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 18:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Joabu dá a lóhùn pé, “Nígbà tí o rí i, kí ló dé tí o kò pa á níbẹ̀ lẹsẹkẹsẹ? Inú mi ìbá dùn láti fún ọ ní owó fadaka mẹ́wàá ati ìgbànú akikanju ninu ogun jíjà.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 18

Wo Samuẹli Keji 18:11 ni o tọ