Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 16:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Dafidi ọba dé Bahurimu, ọkunrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ṣimei, ọmọ Gera, láti inú ìdílé Saulu, jáde sí i, bí ó sì ti ń bọ̀, bẹ́ẹ̀ ni ó ń ṣépè lemọ́lemọ́.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 16

Wo Samuẹli Keji 16:5 ni o tọ