Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 15:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Sadoku, alufaa, wà láàrin wọn, àwọn ọmọ Lefi sì wà pẹlu rẹ̀, wọ́n gbé àpótí ẹ̀rí lọ́wọ́. Wọ́n gbé e kalẹ̀ títí tí gbogbo àwọn eniyan náà fi jáde kúrò ní ìlú. Abiatari, alufaa náà wà láàrin wọn.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 15

Wo Samuẹli Keji 15:24 ni o tọ