Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 15:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ìlú bú sẹ́kún bí àwọn eniyan náà ti ń lọ. Ọba rékọjá odò Kidironi, àwọn eniyan rẹ̀ sì tẹ̀lé e. Gbogbo wọ́n jọ ń lọ sí ọ̀nà apá ijù.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 15

Wo Samuẹli Keji 15:23 ni o tọ