Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 14:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo sì ti mọ̀ lọ́kàn ara mi pé, ọ̀rọ̀ tí kabiyesi bá sọ fún mi yóo fi mí lọ́kàn balẹ̀ nítorí pé, ọba dàbí angẹli Ọlọrun tí ó mọ ìyàtọ̀ láàrin ire ati ibi. OLUWA Ọlọrun rẹ̀ wà pẹlu rẹ̀.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 14

Wo Samuẹli Keji 14:17 ni o tọ