Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 14:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo mọ̀ pé ọba yóo fetí sílẹ̀ láti gbọ́ tèmi, yóo sì gbà mí kalẹ̀ lọ́wọ́ ẹni tí ó fẹ́ pa èmi ati ọmọ mi, tí ó sì fẹ́ pa wá run kúrò lórí ilẹ̀ tí Ọlọrun fún àwọn eniyan rẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 14

Wo Samuẹli Keji 14:16 ni o tọ