Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 14:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Dájúdájú, gbogbo wa ni a óo kú. A dàbí omi tí ó dà sílẹ̀, tí ẹnikẹ́ni kò sì lè kójọ mọ́. Ẹni tí ó bá ti kú, Ọlọrun pàápàá kì í tún gbé e dìde mọ́, ṣugbọn kabiyesi lè wá ọ̀nà, láti fi mú ẹni tí ó bá sá jáde kúrò ní ìlú pada wálé.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 14

Wo Samuẹli Keji 14:14 ni o tọ