Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 14:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Obinrin náà wí pé, “Kí ló dé tí o fi ṣe ohun tí ó burú yìí sí àwọn eniyan Ọlọrun? Ọ̀rọ̀ tí o sọ tán nisinsinyii, ara rẹ gan-an ni o fi dá lẹ́bi, nítorí pé, o kò jẹ́ kí ọmọ rẹ pada wá sílé láti ibi tí ó sá lọ?

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 14

Wo Samuẹli Keji 14:13 ni o tọ