Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 12:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo fún ọ ní ilé oluwa rẹ ati àwọn aya rẹ̀. Mo fi ọ́ jọba lórí Israẹli ati Juda. Ati pé, bí èyí kò bá tó ọ, ǹ bá fún ọ ní ìlọ́po meji rẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 12

Wo Samuẹli Keji 12:8 ni o tọ