Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 12:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Natani bá dá Dafidi lóhùn pé, “Ìwọ gan-an ni ẹni náà. Ohun tí OLUWA Ọlọrun Israẹli sì ní kí n wí fún ọ nìyí; ó ní, ‘Mo fi ọ́ jọba lórí Israẹli, mo sì gbà ọ́ kúrò lọ́wọ́ Saulu.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 12

Wo Samuẹli Keji 12:7 ni o tọ