Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 10:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn ọba tí wọ́n wà lẹ́yìn Hadadeseri rí i pé, àwọn ọmọ Israẹli ti ṣẹgun àwọn, wọ́n bá Israẹli làjà, wọ́n sì ń sìn wọ́n. Láti ìgbà náà ni ẹ̀rù sì ti ń ba àwọn ará Siria láti ran àwọn ará Amoni lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 10

Wo Samuẹli Keji 10:19 ni o tọ