Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 1:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ṣọ̀fọ̀, wọ́n sọkún, wọ́n sì gbààwẹ̀ títí di ìrọ̀lẹ́; nítorí Saulu ati Jonatani, ọmọ rẹ̀, ati àwọn ọmọ Israẹli, eniyan OLUWA nítorí pé ọpọlọpọ wọn ni wọ́n ti pa lójú ogun.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 1

Wo Samuẹli Keji 1:12 ni o tọ