Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sakaraya 11:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ tẹ́tí sílẹ̀, kí ẹ gbọ́ ẹkún àwọn darandaran,nítorí ògo wọn ti díbàjẹ́.Ẹ gbọ́ bí àwọn kinniun ti ń bú ramúramù,nítorí igbó tí wọn ń gbélẹ́bàá odò Jọdani ti parun!

Ka pipe ipin Sakaraya 11

Wo Sakaraya 11:3 ni o tọ