Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 62:10-12 BIBELI MIMỌ (BM)

10. Má gbẹ́kẹ̀lé ìlọ́ni-lọ́wọ́-gbà,má sì fi olè jíjà yangàn;bí ọrọ̀ bá ń pọ̀ sí i, má gbé ọkàn rẹ lé e.

11. Ọlọrun ti sọ̀rọ̀ níbìkan,mo sì ti gbọ́ ọ bí ìgbà mélòó kan pé,Ọlọrun ló ni agbára;

12. ati pé, tìrẹ, OLUWA ni ìfẹ́ tí kì í yẹ̀.Ò máa san ẹ̀san fún eniyangẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ rẹ̀ bá ti rí.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 62