Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 62:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Má gbẹ́kẹ̀lé ìlọ́ni-lọ́wọ́-gbà,má sì fi olè jíjà yangàn;bí ọrọ̀ bá ń pọ̀ sí i, má gbé ọkàn rẹ lé e.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 62

Wo Orin Dafidi 62:10 ni o tọ