N óo mú kí á máa ki oríkì rẹ láti ìran dé ìran;nítorí náà àwọn eniyan yóo máa yìn ọ́ lae ati laelae.