Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 42:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìwọ ọkàn mi, kí ló dé tí o fi rẹ̀wẹ̀sì?Kí ló dé tí ara rẹ kò fi balẹ̀ ninu mi?Gbẹ́kẹ̀ rẹ lé Ọlọrun, nítorí pé n óo tún yìn ín,olùrànlọ́wọ́ mi ati Ọlọrun mi.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 42

Wo Orin Dafidi 42:5 ni o tọ