Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 42:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn nǹkan wọnyi ni mò ń ranti,bí mo ti ń tú ẹ̀dùn ọkàn mi jáde:bí mo ṣe máa ń bá ogunlọ́gọ̀ eniyan rìn,tí mò ń ṣáájú wọn, bí a bá ti ń rìn lọ́wọ̀ọ̀wọ́lọ sí ilé Ọlọrun;pẹlu ìhó ayọ̀ ati orin ọpẹ́,láàrin ogunlọ́gọ̀ eniyan tí ń ṣe àjọ̀dún.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 42

Wo Orin Dafidi 42:4 ni o tọ