Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 40:16-17 BIBELI MIMỌ (BM)

16. Kí gbogbo àwọn tí ń wá ọ máa yọ̀,kí inú wọn sì máa dùn nítorí rẹ;kí àwọn tí ó fẹ́ràn ìgbàlà rẹmáa wí nígbà gbogbo pé, “OLUWA tóbi!”

17. Ní tèmi, olùpọ́njú ati aláìní ni mí;ṣugbọn Oluwa kò gbàgbé mi.Ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ ati olùgbàlà mi,má pẹ́, Ọlọrun mi.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 40