Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 40:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí gbogbo àwọn tí ń wá ọ máa yọ̀,kí inú wọn sì máa dùn nítorí rẹ;kí àwọn tí ó fẹ́ràn ìgbàlà rẹmáa wí nígbà gbogbo pé, “OLUWA tóbi!”

Ka pipe ipin Orin Dafidi 40

Wo Orin Dafidi 40:16 ni o tọ