Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 28:7 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ni agbára ati asà mi,òun ni mo gbẹ́kẹ̀lé;ó ràn mí lọ́wọ́, ọkàn mi sì kún fún ayọ̀;mo sì fi orin ìyìn dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 28

Wo Orin Dafidi 28:7 ni o tọ