Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 28:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Má ṣe kó mi lọ pẹlu àwọn eniyan burúkú,pẹlu àwọn tí ń ṣe iṣẹ́ ibi,àwọn tí ń bá àwọn aládùúgbò wọnsọ ọ̀rọ̀ alaafia,ṣugbọn tí ètekéte ń bẹ ninu ọkàn wọn.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 28

Wo Orin Dafidi 28:3 ni o tọ