Yọ mí kúrò ninu ìhámọ́,kí n lè yin orúkọ rẹ lógo.Àwọn olódodo yóo yí mi ká,nítorí ọpọlọpọ oore tí o óo ṣe fún mi.