Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 123:3-4 BIBELI MIMỌ (BM)

3. Ṣàánú wa, OLUWA, ṣàánú wa,ẹ̀gàn yìí ti pọ̀ jù!

4. Ẹ̀gàn àwọn onírera ti pọ̀ jù fún wa;yẹ̀yẹ́ àwọn onigbeeraga sì ti sú wa.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 123