Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 123:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Wò ó, bí iranṣẹkunrin ti máa ń wo ojú oluwa rẹ̀,tí iranṣẹbinrin sì máa ń wo ojú oluwa rẹ̀,bẹ́ẹ̀ ni à ń wo ojú OLUWA, Ọlọrun wa,títí tí yóo fi ṣàánú wa.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 123

Wo Orin Dafidi 123:2 ni o tọ