Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 114:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Nígbà tí Israẹli jáde kúrò ní ilẹ̀ Ijipti,tí àwọn ọmọ Jakọbu jáde kúrò láàrin àwọn tí ń sọ èdè àjèjì,

2. Juda di ilé mímọ́ rẹ̀,Israẹli sì di ìjọba rẹ̀.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 114