ẹ wo àwọn eniyan burúkú bí wọ́n ti kẹ́ ọfà;wọ́n fa ọrun;wọ́n sì fi òkùnkùn bojú láti ta olódodo lọ́fà.