Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 11:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA ni mo sá di;ẹ ṣe lè wí fún mi pé,“Fò lọ sórí òkè bí ẹyẹ;

2. ẹ wo àwọn eniyan burúkú bí wọ́n ti kẹ́ ọfà;wọ́n fa ọrun;wọ́n sì fi òkùnkùn bojú láti ta olódodo lọ́fà.

3. Nígbà tí ìpìlẹ̀ bá bàjẹ́,kí ni olódodo lè ṣe?”

Ka pipe ipin Orin Dafidi 11