Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 101:7-8 BIBELI MIMỌ (BM)

7. Ẹlẹ́tàn kankan kò ní gbé inú ilé mi;bẹ́ẹ̀ ni òpùrọ́ kankan kò ní dúró níwájú mi.

8. Ojoojumọ ni n óo máa pa àwọn eniyan burúkú run ní ilẹ̀ náà,n óo lé gbogbo àwọn aṣebi kúrò ninu ìlú OLUWA.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 101