N óo máa fi ojurere wo àwọn olóòótọ́ ní ilẹ̀ náà,kí wọ́n lè máa bá mi gbé;ẹni tí ó bá sì ń hu ìwà pípé ni yóo máa sìn mí.