Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 22:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará Moabu ranṣẹ sí àwọn olórí Midiani pé, “Àwọn eniyan wọnyi yóo run gbogbo ohun tí ó wà ní àyíká wa bí ìgbà tí mààlúù bá jẹ koríko ninu pápá.”

Ka pipe ipin Nọmba 22

Wo Nọmba 22:4 ni o tọ