Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 22:3 BIBELI MIMỌ (BM)

ẹ̀rù wọn ba òun ati àwọn eniyan rẹ̀ lọpọlọpọ, nítorí pé wọ́n pọ̀. Jìnnìjìnnì bo gbogbo àwọn ará Moabu nítorí àwọn ọmọ Israẹli.

Ka pipe ipin Nọmba 22

Wo Nọmba 22:3 ni o tọ