Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 22:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà rí angẹli tí ó dúró ní ọ̀nà pẹlu idà ní ọwọ́ rẹ̀, ó yà kúrò ní ojú ọ̀nà sinu igbó. Balaamu lu kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà láti darí rẹ̀ sójú ọ̀nà.

Ka pipe ipin Nọmba 22

Wo Nọmba 22:23 ni o tọ