Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 22:22 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA bínú sí Balaamu nítorí pé ó bá wọn lọ. Bí ó ti ń lọ lórí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀ pẹlu àwọn iranṣẹ rẹ̀ meji, angẹli OLUWA dúró ní ojú ọ̀nà rẹ̀ ó dínà fún un.

Ka pipe ipin Nọmba 22

Wo Nọmba 22:22 ni o tọ