Ní àkókò kan, láti ìlú Heṣiboni,àwọn ọmọ ogun Sihoni jáde lọ bí iná;wọ́n run ìlú Ari ní Moabu,ati àwọn oluwa ibi gíga Arinoni.