Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 7:48-62 BIBELI MIMỌ (BM)

48. àwọn ọmọ Lebana, àwọn ọmọ Hagaba, ati àwọn ọmọ Ṣalimai,

49. àwọn ọmọ Hanani, àwọn ọmọ Gideli, ati àwọn ọmọ Gahari,

50. àwọn ọmọ Reaaya, àwọn ọmọ Resini, ati àwọn ọmọ Nekoda,

51. àwọn ọmọ Gasamu, àwọn ọmọ Usa, ati àwọn ọmọ Pasea,

52. àwọn ọmọ Besai, àwọn ọmọ Meuni, ati àwọn ọmọ Nefuṣesimu,

53. àwọn ọmọ Bakibuki, àwọn ọmọ Hakufa, ati àwọn ọmọ Harihuri,

54. àwọn ọmọ Basiluti, àwọn ọmọ Mehida, ati àwọn ọmọ Hariṣa,

55. àwọn ọmọ Barikosi, àwọn ọmọ Sisera, ati àwọn ọmọ Tema,

56. àwọn ọmọ Nesaya, ati àwọn ọmọ Hatifa.

57. Àwọn ọmọ àwọn iranṣẹ Solomoni nìwọ̀nyí: àwọn ọmọ Sotai, àwọn ọmọ Sofereti, ati àwọn ọmọ Perida,

58. àwọn ọmọ Jaala, àwọn ọmọ Dakoni, ati àwọn ọmọ Gideli,

59. àwọn ọmọ Ṣefataya, àwọn ọmọ Hatili, àwọn ọmọ Pokereti Hasebaimu, ati àwọn ọmọ Amoni.

60. Gbogbo àwọn tí wọn ń ṣe iṣẹ́ iranṣẹ ninu tẹmpili ati àwọn ọmọ àwọn iranṣẹ Solomoni jẹ́ irinwo ó dín mẹjọ (392).

61. Àwọn tí wọ́n wá láti Teli Mela, ati láti Teli Hariṣa, Kerubu, Adoni, ati Imeri, ṣugbọn tí wọn kò mọ ilé baba wọn tabi ibi tí wọ́n ti ṣẹ̀, tí kò sì sí ẹ̀rí tí ó dájú, bóyá ọmọ Israẹli ni wọ́n tabi wọn kì í ṣe ọmọ Israẹli nìwọ̀nyí:

62. àwọn ọmọ Delaaya, àwọn ọmọ Tobaya, ati àwọn ọmọ Nekoda. Wọ́n jẹ́ ojilelẹgbẹta ó lé meji (642).

Ka pipe ipin Nehemaya 7