Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 7:63 BIBELI MIMỌ (BM)

Bákan náà ni àwọn ọmọ alufaa wọnyi: àwọn ọmọ Hobaaya, àwọn ọmọ Hakosi, ati àwọn ọmọ Basilai (tí wọ́n fẹ́ iyawo lára àwọn ọmọ Basilai ará Gileadi, ṣugbọn tí wọn tún ń jẹ́ orúkọ àwọn àna wọn.)

Ka pipe ipin Nehemaya 7

Wo Nehemaya 7:63 ni o tọ