Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 6:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Sanbalati ati Geṣemu ranṣẹ sí mi, wọ́n ní “Wá, jẹ́ kí á pàdé ní ọ̀kan ninu àwọn ìletò tí ó wà ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ Ono.” Ṣugbọn wọ́n ti pète láti ṣe mí ní ibi.

Ka pipe ipin Nehemaya 6

Wo Nehemaya 6:2 ni o tọ