Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 2:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo fún wọn lésì pé, “Ọlọrun ọ̀run yóo mú wa ṣe àṣeyọrí, àwa iranṣẹ rẹ̀ yóo múra, a óo sì mọ odi náà, ṣugbọn ní tiyín, ẹ kò ní ìpín, tabi ẹ̀tọ́, tabi ìrántí ní Jerusalẹmu.”

Ka pipe ipin Nehemaya 2

Wo Nehemaya 2:20 ni o tọ