Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 2:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí Sanbalati ará Horoni ati Tobaya iranṣẹ ọba, ará Amoni ati Geṣemu ará Arabia gbọ́, wọ́n ń fi wá ṣe yẹ̀yẹ́, wọ́n sì ń pẹ̀gàn wa pé, “Kí ni ẹ̀ ń ṣe yìí? Ṣé ẹ̀ ń dìtẹ̀ mọ́ ọba ni?”

Ka pipe ipin Nehemaya 2

Wo Nehemaya 2:19 ni o tọ